Aju Asegun Lo

Raphael A. Macaulay

Verse
Awa ju asegun lo
Nipa ife Oluwa wa
Ati bori ese atiku
Nipa eje Jesu Kristi Oba
Bridge
Awa njoba pelu Jesu
Ninu ogo titi lai
Chorus
Awa ju asegun lo
Awa ti borohun gbogbo
Hallelujah! Hallelujahahah
Hallelujah!
Hallelujah

Lyrics provided by https://agmlyrics.com/