Ogo Ola

-
  • TextText file is a kind of computer file that is structured as a sequence of lines of electronic text.
  • WordUse for Microsoft Office Word or Open Office
  • PDFUse for Abobe Acrobat

Ogo Ola - Kenny K'Ore Lyrics


Download Music Here
Chorus:
Ogo Ola re
Aiku, aisa, aidibaje
Ogo Ola re
Ayeraye o, Oba
Verse 1:
Ka jumo gboruko Jesu ga
(Iwo loba, Iwo loba)
Ki gbogbo angeli juba re
(Iwo loba, Iwo loba)
Let the earth declare your majesty, let them know that you are God
(You are God)
Ki a dobale fun oga ogo, sebiwo lo tunmise eh eh ah
Verse 2:
Seni ki n maa bo?
Seni ki n wa?
Ma bo bata, bee tie ni n bo
Eyin lOba ajiki, ajiyin, ajiun
Eyin lOba ajibo
Eru re n ba mi ooo
Mio to woju re
Mio to korin re
Mio to gbOgo re
Mio to ooo
Eru re n ba mi ooo
Eni to O o si
Eru re n ba mi ooo
Vamp:
(Se lOba awon oba)
Oba awon oba
Olorun awon omo ogun
Gbingbiniki, awuwo ma se gbe
Erujeje ti n migbo kijikiji
Ko i to ooo
Ijo ti mo jo lana (ein)
Orin ti mo ko lana (beeni)
Ope ti mo gbe lana (yes)
Babatunmise! (yeah)
Ko i to ooooo
Outro:
Ogo Ola re o
Aiku, aisa, aidibaje o
Ogo Ola re o
Ayeraye o, Oba
Download Music Here

Ogo Ola lyrics !!!