Afuye Gege

-
  • TextText file is a kind of computer file that is structured as a sequence of lines of electronic text.
  • WordUse for Microsoft Office Word or Open Office
  • PDFUse for Abobe Acrobat

Afuye Gege - Sola Allyson Lyrics


[1] Ibare ni maa faye miju (My days I will use to adore)
Sisin Oo lemi a figba mise (Worshiping you will I use my time for)
Shebi iyen nooni Iyen gangan sha lo da mi fun (It is you, my creator)
Eni ayeraye to nigba mi oo Ogo foo ko Re (Ancient one, I glorify you)
[Chorus]
Afuye gege tio she gbe jigbin ni jigbin ni bi ate ileke (Immeasurable)
Kabiesio mo seba Re Oba to ju gbogbo oba lo/2ce (Majesty to the King of kings)
Mo seba Re o, mo seba Re (I adore You)
Mofori bale mo gbowo soke (I bow in humble adoration)
Mo seba Re o, mo seba Re (I adore You)
Nirele okan mo wa ri (In humble adoration)
Kabiesi o mo seba Re Oba to ju gbogbo oba lo/2x (Majesty to the King of kings)
[2] Talo leso ta lo le ka won, awon irawo towa loju orun (Who can count the stars?)
Egbe isiro leewon ke so fun wa awon erupe inu okun (Who can count the sands in the sea)
Talo le so talo moye ewa iseda toyi wa ka (Who can fathom His creation)
Iyanu fun dudu iyanu fun fufun ()
Ose fe ni to gbon ateni to go
Kaabiesi o mo se ba Re o Oba to ju gbogbo oba lo (Majesty to the King of kings)
[Chorus]
[Bridge]
Afuye gegeti o se gbeIyin Re polokan mi oEmi se ba Re oo..Emi se ba o
Emi se ba mo se ba oo. Mo fori bale mo gbo wo mi soke.Emi seba oo
Ma se bayi dopin igba mi nitori ogo re o. Oba to ju gbogbo oba lo
Gbo gbo aye gbohun soke nimu ewa won, won fogo fooko Re
Ohun gbogbo fiyin fun o o iwo nikan loba tologo
oju mi tiri eti mi ti gbo iyanu re yi aye ka
mogbo ninu eri awon eniyan mimo
mori ninu itan emi gangan onitan
gbogbo ise re dadada ni aburu Kankan o todo Re wa
ohun gbogbo lole yi pada sugbon rara tododo Re ko
kaabie si o moseba Re oo oba toju gbogbo oba lo ee
[Chorus]
Afuye gege mama se gbe
Okan mi pongbe mimoo si (I thirst of Your holiness)
Emi wao mo n wa o si oo hmm
Oba toju gbogbo oba lo ogo Re yi aye ka
Emi seba mo sebaoo, mofori bale niwaju ite aanu (I bow before the throne)
oba agbanilagbatan (Saviour King)
oba adani magbagbe eni
Mo wa riiiiii (I tremble)
Emi seba Re oo oh oh oh
Call: Oba to ju gbogbo oba lo hmmm Resp: Oba to ju gbogbo oba lo
Call: Oba toju gbogbpo oba lo sara Re re ooo
Call: Ehn kayie sio mose baRe o
Call: Emi yio ma fibukun fun o lojojumo iwo nikan loni ii
Call: Ni gbogbo igba ni gbogbo asiko okan mi yio ma fogo fooko re
Call: Oluwa orun ohunaye ewa re yi aye ka anfogo fooko re hmm
Call: Mojewo mojewo re iwonikan loluwa koselomiran leyin re
Call: You are beautiful beyond description ewa re koja ogbon ori
Call: You are wonderful beyond comprehension iyanu re koja oye
Download music here
Thanks to Cypress for this lyrics
 

Afuye Gege lyrics !!!