Oluwa O tobi

-
  • TextText file is a kind of computer file that is structured as a sequence of lines of electronic text.
  • WordUse for Microsoft Office Word or Open Office
  • PDFUse for Abobe Acrobat

Oluwa O tobi - Tope Alabi Lyrics


Oluwa o tobi
o tobi o, o tobi ×2
koseni tale fi safiwe re o
o tobi o, ko seda tale fi sakawe re o
o tobi o oluwa ×2
O tobi o, oluwa giga
lorile ede gbogbo
gbigbega ni o
pupopupo ni o
o koja omi okun
atosa o ga po
ajulo ose julo
Oba Lori aye o tobi o eh
agbani loko eru
olominira ton deni lorun
ofi titobi gba mi
lowo ogun tapa obi mi oka
olugbeja mi to ba rogun
lalai mu mi lo to segun
Akoni ni o
Boti tobi to oo
lanu re tobi
boti tobi se o
lododo re tobi o
o tobi tife tife
oni majemu ti kii ye
Aro nla to gbo jije minu
aye gbogbo alai le tan
ogbon to koja ori aye gbogbo ooo
akoko otobi, o tobi o
Oluwa
Ipilese ogbori o yeye
O Tobi
Ibere eni to fogbon da ohun gbogbo
Oluwa
Igbeyin ola nla, o lala oo
O Tobi
Opin aye atorun kosi rure
Oluwa
O tobi o se sakawe lailai o
O tobi
Agbagba merinlelogun nki o tobi
Oluwa
Awon angeli won ki o o tobi
O Tobi
Olorun Elijah Oludele Abina
Oluwa
Oma tobi laye mi o tobi ooo
O tobi

Oluwa O tobi lyrics !!!