Solo 1
Iwo lo wa kemi le joba, kemi le dade, kemi le laiye
Iwo labi lati gba mi, lati fa mi sinu imole
Iwo laabi taa koda, lati wa gba wa, Iwo lOba, Iwo lOba
Chorus:
Abi fese re, fese mi, fese wa
Abi ka le ni iye aiyeraiye (Repeat)
Iwo lo wa kawa le joba, kawa le dade, kawa le laiye
Iwo labi lati gba wa, lati fa wa sinu imole
Iwo taabi taa koda, lati wa gba wa, Iwo lOba, Iwo lOba
Iwo lo wa lati ferin lati forin ayo saiye mi,
Iwo lemi yoo maa sin lemi yoo ma yin Olorun Orun
Iwo labi lati gba mi, lati wa fa mi sinu imole
Iwo taabi taa ko da, lati wa gba wa, Iwo lOba, iwo lOluwa
Chorus:
Abi fese re, fese mi, fese wa
Abi ka le ni iye aiyeraiye (Repeat)
Interlude
Bridge:
Dide ki o korin Ife Olorun, Ogo folorun loke orun
Awon angeli nkorin, awa eda aye ngberin
A wa pelu ebun iyebiye, pelu orin iyin ti ko niye
A fope fun Olorun wa, fun fe nla to fife wa
E mu ade oba re wa, ogo foba tabi.
Chorus till fade
Download song here