Mo wo yika aye
Oke oun petele
Alagbara ni o
Oba toti wa tele
Unshakeable
Unmovable
Unstoppable God
Talabafi O we o
Oba ti nki gbabetele
Ana, oni, ola o
Oba to ti wa tele
Reliable, Dependable, Unsearchable God
Mo wo le
Mo juba Re
Talabafi O we
Kosi ooo
Talabafi O we eh eh eh
Talabafi O we eh
Talabafi O we
Kosi oo
Talabafi O we eh o
All:
Talabafi O we
Kosi oo
Talabafi O we
(Sebeyin loba to gbon) Eyin lOba to gbon
(Ti ogbon kori mu) Ti ogbon kori mu
(SebEyin loba to mo) Eyin lOba to mo
(Ti imo ole pa) Ti imo ole pa
Arugbo Ojo
Aseda orun
Eyin latobiju
Lead: Eyin latobiju
(Sebeyin) Oba to ta sanmo
bi eni teni
(O fi gbogbo aye) O fi aye o, sapoti itise re
Aribiti, Arabata
Eyin latobiju
Lead: Talabafi O we
Oluwa a, Oluwa, Oluwa, Oluwa wa
Oruko Re ti niyin to ni gbogbo aye
Iwo ti O gbe Ogo Re ka ori awon orun
Lati enu awon omo owo, titi de enu omo irinse, ni wontiun se ilana agbara
Kabieyin o si, Kabio o si, Kabieyin o si, Kabiyesi iyin Re,
Onile kangunkangun ode orun
Oro to ju oro tole jade lenu ologbon to ga ju laye
Oba ti o ti wa tele, kosi ni gba abetele lailai o
Emi ama pe e lolorioko gafata, Olori ogun orun
Ijaya faraye, Iberu fun gbogbo awon omo adari hurun
Iwo ni, Iwo ni
Oba nla, Oba nla, Tiun seun nla, too lagbara nla, Oba mi Alagbara orun
toolagbara lati gba agbara lowo alagbara aye
Ogo fun O o, Kabiyesi o, Oba awon oba, Iba o o, Iba a
No god like You
No king like You
And no man like You, Lord
Talabafi O we, Talabafi O we
All:
No man like You
No king like You
No god like You
Talabafi O we, Talabafi O we