Atobiju

-
  • TextText file is a kind of computer file that is structured as a sequence of lines of electronic text.
  • WordUse for Microsoft Office Word or Open Office
  • PDFUse for Abobe Acrobat

Atobiju - Ola Onabajo Lyrics


Chorus
Olorun wa,
Ayeraye mo gbe o ga o
Mimo mimo Atobiju
Eyin nikan logo ola ye fun
Verse 1 Ola
From the rising of the sun
Unto its going down
Mi o reni to jo o
Ti mole fi o we
Ologo ara nla, toni gbogbo ogo
Ashiwere wipe, Olorun kosi
Noje ba won so, Nitori moti mo o
Olola Ni JESU mi, ewa re koja oye
Baba o ni bebe, sa ma toju mi lo
Olorun Baba Agba Oye.
Chorus
Olorun wa,
Ayeraye mo gbe o ga o
Mimo mimo Atobiju
Eyin nikan logo ola ye fun
Adeyinka o ya now
Verse 2 Adeyinka Alaseyori
Iyin re o le dawo duro, lenu MI Oluwa
Iba re Akoda Aye, Aseda lode orun
Asaju Ogun la lo, Akehin Ogun loje
Paripari Ola, Alebe ilu a sasi
O da wa si,
O pa wa mo
Olore e e e
Iwonikan lawa gbe ga
Iwonikan lawa pe bo
From the beginning of our lives
Till this very moment
Eh Eh Eh, Youve been faithful
Ever faithful God
Chorus
Olorun wa,
Ayeraye mo gbe o ga o
Mimo mimo Atobiju
Eyin nikan logo ola ye fun
Drums Interlude
Bridge
Call: E ba nkira, E ba nkira, E ba nkira fun
Response: E ba nkira 3x
Olori Aye gbogbo E ba nkira fun
Tomu riri jade ninu airi E ba nkira fun
Orisun Ayomi loje E ba nkira fun
O ni ole ojo merin dide Baba E ba nkira fun
O mu omi jade lati inu apata E ba nkira fun
O rin Lori omi, sibe ko ri E ba nkira fun
Ake to bo sinu omi, igi lofi gbe jade E ba nkira fun
JESU Olugbala o wo odi Jericho E ba nkira fun
Talaka wa Lo jeun pelu awon Oba E ba nkira fun
Ari na Ari Lo wa di ohun igbagbe E ba nkira fun
Agan ojo pipe, won di Iya olomo E ba nkira fun
Kosi ohun to soro se fun Olorun Bami E ba nkira fun
Ah Ah ATOBIJU
E ba nkira fun.

Atobiju lyrics !!!