Temi Asese

-
  • TextText file is a kind of computer file that is structured as a sequence of lines of electronic text.
  • WordUse for Microsoft Office Word or Open Office
  • PDFUse for Abobe Acrobat

Temi Asese - Oluwabunmi Oladejo Lyrics


VERSE 1
won ko rawon jopo simi
won bimipe talofebamise
wonwi lokan arawon pe
koma senikan tole bami se temi
wonti gbagbe pe mololuwa
molo oluwa nbe olagbara
owo oluwa komakuru
lati gbami lowo gbogbo asebi
eti oluwa komama di
lati gbo gbogbo aroye mi
BRIDGE
ki oluwa ko ranmi lowo
ki nle bori awon ota mi(2ce)
CHORUS
temi asese loruko jesu asese(4ce)
VERSE 2
Botiwu kogun aye poto
momo daju pe mabiri ogun
gbogun tawon toun gbogun timi
fija fawon toun nimilara
oluwa lolusho aguntan mi
emi ki yo beru ohun kan
owo oluwa komakuru
lati gbami lowo gbogbo asebi
eti oluwa komama di
lati gbo gbogbo aroye mi
BRIDGE
ki oluwa ko ranmi lowo
ki nle bori awon ota mi(2ce)
CHORUS
temi asese loruko jesu asese(4ce)owo oluwa komakuru
lati gbami lowo gbogbo asebi
eti oluwa komama di
lati gbo gbogbo aroye mi
BRIDGE
ki oluwa ko ranmi lowo
ki nle bori awon ota mi(2ce)
temi asese loruko jesu asese(4ce)

Temi Asese lyrics !!!