ChorusNinu afe ayeBaba jnle tele oNinu afe ile ayeJe nle tele oVerse 1What shall it profit a man to gain the world and lose his soul.Ile aye yii dun ladunjuSugbon igbeyin re koro bi iwoIle aye baje o balumoO olu orun dakun maje siseMaje fi adun ileaye o baba miKi n fi ba ti orunjeKo si bi aye tile dun toOrun a dun ju ile aye loRepeat ChorusVerse 2The heart is deceitful above all things and desperately wicked who I mean who can know itOrun o gbe eIro laye mo nAfojo boriElesan wo o lorunIdajo o le ro Iku lere eseEda adariwurunEeje a sora siwa wuKa mo ba oja jeKa tun ba ale jeE ni awo e gbodo woranchorus