Aju Asegun Lo

-
  • TextText file is a kind of computer file that is structured as a sequence of lines of electronic text.
  • WordUse for Microsoft Office Word or Open Office
  • PDFUse for Abobe Acrobat

Aju Asegun Lo - Raphael A. Macaulay Lyrics


Verse
Awa ju asegun lo
Nipa ife Oluwa wa
Ati bori ese atiku
Nipa eje Jesu Kristi Oba
Bridge
Awa njoba pelu Jesu
Ninu ogo titi lai
Chorus
Awa ju asegun lo
Awa ti borohun gbogbo
Hallelujah! Hallelujahahah
Hallelujah!
Hallelujah

Aju Asegun Lo lyrics !!!

Raphael A. Macaulay Lyrics