Àlùjanjankíjan

-
  • TextText file is a kind of computer file that is structured as a sequence of lines of electronic text.
  • WordUse for Microsoft Office Word or Open Office
  • PDFUse for Abobe Acrobat

Àlùjanjankíjan - Sola Allyson Lyrics


Iya iya takun wale, Alujanjankijan
Iya iya takun wale, Alujanjankijan
E ma fomo sile fun iya je, Alujanjankijan
Eni to bimo loye ko womo, Alujanjankijan
[Sola Allyson]
Bami nan momi ye ko denu olomo
Oju merin lon bimo sugbon igba oju lon womo
Omo tao ko, a gbe ile ta ko ta
Omo tao ko, a ko eso tani ta
Omo nigbeyin, Omo lola, Omo lola
Omo niyi, Omo lade, Omo lewa, Omo leso oo
Oda bioda, o le da
O san bio san, a de san
Igboya ati adura ni yio gba
Yio da
Iya iya takun wale, Alujanjankijan
Iya iya takun wale, Alujanjankijan
E ma fomo sile fun iya je, Alujanjankijan
Eni to bimo loye ko womo (e tomo), Alujanjankijan
[Adekunle Gold]
Ori funmi lomo rere bi ti Samuel o
Won kosa fun o gbe eko o
If you spare the rod you go spoil the child I hope you know ooo
Train them with the love of God I beg oooo
Tori alaigboran omo, asa ni
Agba o jo won loju, asa ni
Agbaya ni o da, asa ni
Alaigboran omo o, omo ni
Won le deyan lola, omo ni
Ta ba ko won dada, omo ni
Won le deyan lola, omo ni
Iya iya takun wale, Alujanjankijan
Iya iya takun wale, Alujanjankijan
Eni to bimo lo ye ko womo, Alujanjankijan
E ma fomo sile fun iya je, Alujanjankijan
Iya iya takun wale, Alujanjankijan
Iya iya takun wale, Alujanjankijan
E ma fomo sile fun iya je, Alujanjankijan
Eni to bimo lo ye ko womo, Alujanjankijan
E ma fomo sile fun iya je, Alujanjankijan
Iya baba takun wale, Alujanjankijan
Kekere lati npa eka iroko
To ba dagba tan ebo ni yio ma gba
Ohun ta bi fi sile lewure ngbe
Kewure aye ma ma gbe wa lomo lo
Omo ta o ro ekun aye a gbe lo
Kekun aye ma ma gbe wa lomo lo
Iya Iya takun wale, Alujanjankijan
Iya Iya takun wale, Alujanjankijan

Àlùjanjankíjan lyrics !!!