Yes and Amen

-
  • TextText file is a kind of computer file that is structured as a sequence of lines of electronic text.
  • WordUse for Microsoft Office Word or Open Office
  • PDFUse for Abobe Acrobat

Yes and Amen - Tope Alabi Lyrics


Amin Ase ida a lamo o
Eni ti o ni a padanu
Iba o to to olu Imo o
Eni ti o ni o, ko ni nkankan o
(Amin aseda)
Eni ti o ni o, ko ni nkankan o
Eni ti o ni o, ko ni nkankan
(Ko ni nkankan)
Eni ti o ni o, ko ni nkankan o
(Oooooooo)
Eni ti o ni o, ko ni nkankan
(E ko ni nkankan o)
Mo wa ri foba to ni di da aiye eeee
Ibare mare e, oni gbede orun
Iwo to ni gbogbo aiye ni ikawo
Bo ti doyi kato
Iba oni mo to ga ju ee
Baba ni baba se
(Amin ase ida mo gbe ba fun)
Amin ase ida la mo o
(Eni ti o ni o ke)
Eni ti o ni a padanu
(Adanu nla lo pa laye, lorun)
Iba o toto olu imo
(A ton ton to, mo ri ba, mori ba o)
Eni ti o ni o ko ni nkankan
(Ko ni nkankan)
Eni ti o ni o ko ni nkankan o
(E ma ni penre labo)
Eni ti o ni o, ko ni nkankan
(Ko ni kini nkan lagbon)
Eni ti…

Yes and Amen lyrics !!!